Psalms 40:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jẹ́ kí jìnnìjìnnì bò wọ́n, kí wọ́n sì gba èrè ìtìjú, àní, àwọn tí ń ṣe jàgínní mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki nwọn ki o di ofo fun ère itiju wọn, awọn ti nwi fun mi pe, A! a!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí àwọn tí ó wí fún mi pé, “Áà! Áá!” ó di ẹni àfọwọ́ rọ́ sẹ́yìn nítorí ìtijú wọn.