Psalms 40:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni mo wí pé, “Wò ó, mo dé; a ti kọ nípa mi sinu ìwé pé:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni mo wipe, Kiyesi i, emi de: ninu àpo-iwe nì li a gbe kọwe mi pe,
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni mo wí pé, “Èmi nìyí; nínú ìwé kíkà nì a kọ ọ nípa temí wí pé.