Psalms 41:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí n lè mọ̀ pé o fẹ́ràn mi, nígbà tí ọ̀tá kò bá borí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nipa eyi ni mo mọ̀ pe iwọ ṣe oju-rere si mi, nitoriti awọn ọta mi kò yọ̀ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi mọ̀ pé inú Rẹ̀ dùn sí mi, nítorí ọ̀tá mi kò borí mi.