Psalms 41:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọ̀tá mi ń ro ibi sí mi, wọ́n ń wí pé, “Nígbà wo ni yóo kú, tí orúkọ rẹ̀ yóo parẹ́?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọta mi nsọ ibi si mi pe, nigbawo ni on o kú, ti orukọ rẹ̀ yio si run?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀ta mi ń sọ́rọ̀ mi nínú arankan, pé “Nígbà wo ni yóò kú ti orúkọ Rẹ̀ yóò sì run?”