Psalms 41:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo àwọn tí ó kórìíra mi jọ ń sọ̀rọ̀ wújẹ́wújẹ́ nípa mi; ohun tó burú jùlọ ni wọ́n ń rò sí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn ti o korira mi jumọ nsọ̀rọ kẹlẹ́ si mi: emi ni nwọn ngbìmọ ibi si.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọ̀tá mi gbìmọ̀ papọ̀ nípa mi; èmi ni wọn ń gbìmọ̀ ibi sí,