Psalms 42:10 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ọgbẹ́ aṣekúpani ni ẹ̀gàn àwọn ọ̀tá mi rí lára mi, nígbà tí wọn ń bi mí lemọ́lemọ́ pé, “Níbo ni Ọlọrun rẹ wà?”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi ẹnipe idà ninu egungun mi li ẹ̀gan ti awọn ọta mi ngàn mi; nigbati nwọn nwi fun mi lojojumọ pe, Ọlọrun rẹ dà?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ẹni pé idà egungun mi ni ẹ̀gàn tí àwọn ọ̀ta mi ń gàn mí, Bí wọn ti ń béèrè ni gbogbo ọjọ́. “Níbo ni Ọlọ́run Rẹ wà?”