Psalms 42:8 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ní ọ̀sán, OLUWA fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ hàn, ní òru, orin rẹ̀ gba ẹnu mi, àní, adura sí Ọlọrun ìyè mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Oluwa yio paṣẹ iṣeun-ifẹ rẹ̀ nigba ọ̀san, ati li oru orin rẹ̀ yio wà pẹlu mi, ati adura mi si Ọlọrun ẹmi mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọ̀sán ní OLÚWA ran ìfẹ́ Rẹ̀, àti ni àṣálẹ́ ni orin Rẹ̀ wà pẹ̀lú mi àdúrà sí Ọlọ́run ayé mi.