Psalms 43:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí ìwọ ni Ọlọrun tí mo sá di. Kí ló dé tí o fi ta mí nù? Kí ló dé tí mo fi ń ṣọ̀fọ̀ kiri nítorí ìnilára ọ̀tá?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori iwọ li Ọlọrun agbara mi: ẽṣe ti iwọ fi ṣa mi tì? ẽṣe ti emi fi nrìn ni igbawẹ nitori inilara ọta nì.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ ni Ọlọ́run ibi agbára mi. Èéṣe tí ìwọ fi kọ̀ mi sílẹ̀? Èéṣe tí èmi yóò máa rìn nínú ìbìnújẹ́, nítorí ìnilára lọ́dọ̀ àwọn ọ̀tá?