Psalms 43:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nígbà náà ni n óo lọ sí ibi pẹpẹ Ọlọrun, àní, sọ́dọ̀ Ọlọrun, ayọ̀ ńlá mi. Èmi óo sì yìn ọ́ pẹlu hapu, Ọlọrun, Ọlọrun mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana li emi o lọ si ibi pẹpẹ Ọlọrun, sọdọ Ọlọrun ayọ̀ nla mi: nitõtọ, lara duru li emi o ma yìn ọ, Ọlọrun, Ọlọrun mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ní èmi o lọ sí ibi pẹpẹ Ọlọ́run, sí Ọlọ́run ayọ̀ mí àti ìdùnnú mi, èmi yóò yin ọ pẹ̀lú dùùrù, ìwọ Ọlọ́run, Ọlọ́run mi.