Psalms 44:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
O ti ṣe wá bí aguntan lọ́wọ́ alápatà, o sì ti fọ́n wa káàkiri àwọn orílẹ̀-èdè.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ ti fi wa fun jijẹ bi ẹran agutan; iwọ si ti tú wa ka ninu awọn keferi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ fi wá fún jíjẹ bí ẹran àgùntàn Ìwọ sì ti tú wa ká sí àárin àwọn aláìkọlà.