Psalms 44:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo nǹkan yìí ló ṣẹlẹ̀ sí wa, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé a kò gbàgbé rẹ, bẹ́ẹ̀ ni a kò yẹ majẹmu rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Gbogbo wọnyi li o de si wa; ṣugbọn awa kò gbagbe rẹ, bẹ̃li awa kò ṣe eke si majẹmu rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn nǹkan wọ̀nyí ń ṣẹlẹ̀ sí wa, ṣíbẹ̀ àwa kò gbàgbé Rẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni a kò ṣèké sí májẹ̀mu Rẹ̀.