Psalms 44:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
sibẹ o fọ́ wa túútúú fún ìjẹ àwọn ẹranko, o sì fi òkùnkùn biribiri bò wá mọ́lẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi iwọ tilẹ ti fọ́ wa bajẹ ni ibi awọn ikõkò, ti iwọ si fi ojiji ikú bò wa mọlẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n wọ́n kọ lù wá, ìwọ sì sọ wá di ẹran ọdẹ fún àwọn ajáko tí wọn sì fi òkùnkùn biribiri bò wá mọ́lẹ̀.