Psalms 45:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ará Tire yóo máa fi ẹ̀bùn wá ojurere rẹ, àní, àwọn eniyan tí wọ́n ní ọrọ̀ jùlọ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọmọbinrin Tire ti on ti ọrẹ; ati awọn ọlọrọ̀ ninu awọn enia yio ma bẹ̀bẹ oju-rere rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọmọbìnrin ọba tirẹ̀ yóò wá pẹ̀lú ẹ̀bùn àwọn ọkùnrin ọlọ́rọ̀ yóò máa wá ojú rere Rẹ̀.