Psalms 45:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yóo máa wá ojurere rẹ, pẹlu oríṣìíríṣìí ọrọ̀. Ọmọ ọbabinrin fi aṣọ wúrà ṣọ̀ṣọ́ jìngbìnnì ninu yàrá rẹ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti ogo ti ogo li ọmọbinrin ọba na ninu ile: iṣẹ wura ọnà abẹrẹ li aṣọ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo ògo ni ti ọmọbìnrin ọba ní àárin ilé Rẹ̀ aṣọ ìbalẹ̀ Rẹ̀ a ṣe é lọ́sọ̀ọ́ pẹ̀lú wúrà