Psalms 45:16 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọkunrin rẹ ni yóo rọ́pò àwọn baba rẹ; o óo fi wọ́n jọba káàkiri gbogbo ayé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nipò awọn baba rẹ li awọn ọmọ rẹ yio wà, ẹniti iwọ o ma fi jẹ oye lori ilẹ gbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọmọ Rẹ̀ ni yóò gba ipò baba Rẹ̀ ìwọ yóò sì fi wọ́n joyè lórí ilẹ̀ gbogbo.