Psalms 45:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo mú kí á máa ki oríkì rẹ láti ìran dé ìran; nítorí náà àwọn eniyan yóo máa yìn ọ́ lae ati laelae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o ma ṣe orukọ rẹ ni iranti ni iran gbogbo: nitorina li awọn enia yio ṣe ma yìn ọ lai ati lailai.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmí yóò máa rántí orúkọ Rẹ̀ ní ìran gbogbo nígbà náà ni orílẹ̀ èdè yóò yìn ọ́ láé àti láéláé.