Psalms 45:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọfà rẹ mú, wọ́n gún àwọn ọ̀tá ọba lọ́kàn, àwọn eniyan ń wó lulẹ̀ níwájú rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọfa rẹ mu li aiya awọn ọta ọba; awọn enia nṣubu nisalẹ ẹsẹ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí ọfà mímú Rẹ̀ dá ọkàn àwọn ọ̀tá ọba lu jẹ́ kí àwọn orílẹ̀ èdè ṣubú sí abẹ́ ẹsẹ̀ Rẹ̀