Psalms 45:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ọmọ ọba wà lára àwọn obinrin inú àgbàlá rẹ, ayaba dúró ní ọwọ́ ọ̀tún rẹ, ó fi ojúlówó wúrà ṣe ọ̀ṣọ́ sára.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọbinrin awọn alade wà ninu awọn ayanfẹ rẹ: li ọwọ ọtún rẹ li ayaba na gbe duro ninu wura Ofiri.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ọmọbìnrin àwọn aládé wà nínú àwọn àyànfẹ́ Rẹ̀ ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀ ni ayaba náà gbé dúró nínú wúrà ófórì.