Psalms 46:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun ni ààbò ati agbára wa, olùrànlọ́wọ́ tí ó wà nítòsí nígbà gbogbo, ní ìgbà ìpọ́njú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ỌLỌRUN li àbo wa ati agbara, lọwọlọwọ iranlọwọ ni igba ipọnju.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run ni ààbò àti agbára wa ó jẹ́ olùrànlọ́wọ́ nínú ìgbà ìpọ́njú.