Psalms 46:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà ẹ̀rù kò ní bà wá bí ayé tilẹ̀ ṣídìí, bí àwọn òkè ńlá tilẹ̀ ṣípò pada, tí wọ́n bọ́ sinu òkun;
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina li awa kì yio bẹ̀ru, bi a tilẹ ṣi aiye ni idi, ti a si ṣi awọn oke nla nipò lọ si inu okun:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítori náà àwa kì yóò bẹ̀rù, bí a tilẹ̀ sí ayé ní ìdí tí òkè sì ṣubú sínú òkun