Psalms 46:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Inú àwọn orílẹ̀-èdè ń ru, àwọn ìjọba ayé ń gbọ̀n; OLUWA fọhùn, ayé sì yọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn keferi nbinu, awọn ilẹ ọba ṣidi: o fọhun rẹ̀, aiye yọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn orílẹ̀ èdè ń bínú, àwọn ilẹ̀ ọba subú ó gbé ohun Rẹ̀ sókè, ayé yọ̀.