Psalms 46:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA àwọn ọmọ ogun wà pẹlu wa; Ọlọrun Jakọbu ni ààbò wa.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa awọn ọmọ-ogun wà pẹlu wa; Ọlọrun Jakobu li àbo wa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run awọn ọmọ ogún wà pẹ̀lú wa Ọlọ́run Jákọ́bù ni ààbò wa