Psalms 47:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí Ọlọrun ni Ọba gbogbo ayé; Ẹ fi gbogbo ohun èlò ìkọrin kọ orin ìyìn!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori Ọlọrun li Ọba gbogbo aiye: ẹ fi oye kọrin iyìn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí Ọlọ́run ni ọba gbogbo ayé ẹ kọrin ìyìn pẹ̀lú Sáàmù!