Psalms 47:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọlọrun jọba lórí gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè; Ó gúnwà lórí ìtẹ́ mímọ́ rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọlọrun jọba awọn keferi: Ọlọrun joko lori itẹ ìwa-mimọ́ rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run jọba lórí gbogbo ayé; Ọlọ́run jókòó lórí ìtẹ́ ìwà mímọ́ Rẹ̀