Psalms 47:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn ìjòyè orílẹ̀-èdè kó ara wọn jọ pẹlu àwọn eniyan Ọlọrun Abrahamu. Ọlọrun ni aláṣẹ gbogbo ayé; òun ni ọlọ́lá jùlọ!
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn alade awọn enia kó ara wọn jọ, ani awọn enia Ọlọrun Abrahamu: nitori asà aiye ti Ọlọrun ni: on li a gbe leke jọjọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn aládé ayé kó ara wọn jọ gẹ́gẹ́ bí ènìyàn Ọlọ́run Ábúráhámù nítorí asà ayé ti Ọlọ́run ni òun ni ó ga jùlọ.