Psalms 48:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jẹ́ kí inú òkè Sioni kí ó dùn, kí gbogbo Juda sì máa yọ̀ nítorí ìdájọ́ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki òke Sioni ki o yọ̀, ki inu awọn ọmọbinrin Juda ki o dùn, nitori idajọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí òkè Síónì kí ó yọ̀ kí inú àwọn ọmọbìnrin Júdà kí ó dùn nítorí ìdájọ́ Rẹ̀.