Psalms 48:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó! Àwọn ọba kó ara wọn jọ; wọ́n jùmọ̀ gbógun tì í.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Sa wò o, awọn ọba pejọ pọ̀, nwọn jumọ nkọja lọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí àwọn ọba kógun jọ pọ̀ wọ́n jùmọ̀ ń kọjá lọ