Psalms 49:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yóo rí i pé ikú a máa pa ọlọ́gbọ́n, òmùgọ̀ ati òpè a sì máa rọ̀run; wọn a sì fi ọrọ̀ wọn sílẹ̀ fún ẹlòmíràn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori o nri pe awọn ọlọgbọ́n nkú, bẹ̃li aṣiwere ati ẹranko enia nṣegbe, nwọn si nfi ọrọ̀ wọn silẹ fun ẹlomiran.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ọ̀pọ̀ ènìyàn rí ọkùnrin ọlọ́gbọ́n tí ó kú bẹ́ẹ̀ ni aṣiwèrè àti aláìlọ́gbọ́n pẹ̀lú sègbé wọ́n sì fi ọrọ̀ wọn sílẹ̀ fún ẹlòmíràn