Psalms 49:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Eniyan kò lè máa gbé ninu ọlá rẹ̀ títí ayé, bí ẹranko tíí kú, ni òun náà óo kú.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn enia ti o wà ninu ọlá kò duro pẹ: o dabi ẹranko ti o ṣegbé.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ọkùnrin tí o wà nínú ọlá kò dúró pẹ́ o sì dàbí ẹranko tí o sègbé