Psalms 49:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìpín àwọn tí ó ní igbẹkẹle asán nìyí, òun sì ni èrè àwọn tí ọrọ̀ wọn tẹ́ lọ́rùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ipa ọ̀na wọn yi ni igbẹkẹle wọn: ọ̀rọ wọn si tọ́ li oju awọn ọmọ wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èyí ni òtítọ́ àwọn ènìyàn tí o gbàgbọ́ nínú ara wọn, àti àwọn tí ń tẹ̀lé wọn, tí o gba ọ̀rọ̀ wọn. Sela