Psalms 49:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn Ọlọrun yóo ra ẹ̀mí mi pada lọ́wọ́ ikú nítorí pé yóo gbà mí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Ọlọrun ni yio rà ọkàn mi lọwọ isa-okú: nitoripe on o gbà mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ọlọ́run yóò ra ọkàn mi padà kúrò nínú isà òkú yóò gbé mi lọ sọ́dọ̀ òun fún rara Rẹ̀.