Psalms 49:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
àwọn tí wọ́n gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ wọn, tí wọ́n sì ń yangàn nítorí wọ́n ní ọrọ̀ pupọ?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ti o gbẹkẹle ọrọ̀ wọn, ti nwọn si nṣe ileri li ọ̀pọlọpọ ọrọ̀ wọn;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn tí o gbẹ́kẹ̀lé ọrọ̀ wọn tí wọn sì ń ṣe ìlérí ni ọpọlọpọ ọrọ̀ wọn