Psalms 5:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí ìwọ OLUWA a máa bukun àwọn olódodo; ò sì máa fi ojurere rẹ tí ó dàbí apata dáàbò bò wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori iwọ, Oluwa, ni yio bukún fun olododo; oju-rere ni iwọ o fi yi i ka bi asà.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dájúdájú, OLÚWA, ìwọ bùkún olódodo; ìwọ fi ojú rere Rẹ yí wọn ká bí àṣà.