Psalms 5:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
OLUWA, tọ́ mi sọ́nà òdodo rẹ, nítorí àwọn ọ̀tá mi; jẹ́ kí ọ̀nà rẹ hàn kedere níwájú mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tọ́ mi, Oluwa, ninu ododo rẹ, nitori awọn ọta mi: mu ọ̀na rẹ tọ́ tàra niwaju mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tọ́ mi, OLÚWA, nínú òdodo Rẹ, nítorí àwọn ọ̀ta mi, mú ọ̀nà Rẹ tọ́ níwájú mi.