Psalms 5:9 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí kò sí òtítọ́ kan lẹ́nu wọn; ìparun ni ó wà ninu ọkàn wọn. Isà òkú tí ó yanu sílẹ̀ ni ọ̀fun wọn; ẹnu wọn kún fún ìpọ́nni ẹ̀tàn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori ti otitọ kan kò si li ẹnu ẹnikẹni wọn; ikakika ni iha inu wọn; isa-okú ti o ṣi silẹ li ọfun wọn; ahọn wọn ni nwọn fi npọ́nni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò sí ọ̀rọ̀ kan ní ẹnu wọn tí a lè gbàgbọ́; ọkàn wọn kún fún ìparun. ọ̀nà ọ̀fun wọn ni iṣà òkú tí ó sí sílẹ̀; pẹ̀lú ahọ́n wọn ni wọ́n ń sọ ẹ̀tàn.