Psalms 50:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Bí ebi bá tilẹ̀ pa mí, ẹ̀yin kọ́ ni n óo sọ fún, nítorí èmi ni mo ni gbogbo ayé ati àwọn nǹkan tí ó wà ninu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Bi ebi npa mi, emi kì yio sọ fun ọ: nitori pe aiye ni ti emi, ati ẹkún inu rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ebi tílẹ̀ ń pá mí, èmi kì yóò sọ fún ọ, nítorí ayé ni tèmi àti ohun gbogbo tí ó wa ní inú Rẹ̀.