Psalms 50:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn Ọlọrun bi àwọn eniyan burúkú pé, “Ẹ̀tọ́ wo ni ẹ níláti máa ka àwọn òfin mi, tabi láti máa mú ẹnu ba ìlànà mi?
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn Ọlọrun wi fun enia buburu pe, Kini iwọ ni ifi ṣe lati ma sọ̀rọ ilana mi, tabi ti iwọ fi nmu majẹmu mi li ẹnu rẹ?
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ọlọ́run sọ fún àwọn ènìyàn búburú: “Kí ní ẹ̀tọ́ tí o ní tí ìwọ fi ń tún àwọn ìlànà mi sọ tàbí tí ìwọ sì ń sọ májẹ̀mu mi ní ẹnu Rẹ?