Psalms 50:18 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Tí ẹ bá rí olè, ẹ̀yin pẹlu rẹ̀ a dọ̀rẹ́; ẹ sì ń bá àwọn panṣaga kẹ́gbẹ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbati iwọ ri olè, nigbana ni iwọ ba a mọ̀ ọ pọ̀, iwọ si ba awọn àgbere ṣe ajọpin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà tí ìwọ rí olè, ìwọ dára pọ̀ mọ́-ọn ìwọ sì da ara Rẹ̀ dé àwọn alágbèrè