Psalms 50:21 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Gbogbo nǹkan wọnyi ni ẹ ti ṣe tí mo sì dákẹ́; ẹ wá ń rò ninu yín pé, èmi yín rí bákan náà. Ṣugbọn nisinsinyii mò ń ba yín wí, mo sì ń fi ẹ̀sùn kàn yín.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nkan wọnyi ni iwọ ṣe emi si dakẹ; iwọ ṣebi emi tilẹ dabi iru iwọ tikararẹ; emi o ba ọ wi, emi o si kà wọn li ẹsẹ-ẹsẹ ni oju rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn nǹkan wọ̀nyí ni ìwọ ti ṣe, mo sì dákẹ́; ìwọ rò pé mo jẹ́ irú kan náà bí ìrẹ, ṣùgbọ́n èmi yóò bá ọ wí èmi yóò sì fi ẹ̀sùn kàn ọ́ ní ojú ara Rẹ.