Psalms 50:8 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N kò ba yín wí nítorí ẹbọ rírú; nígbà gbogbo ni ẹ̀ ń rú ẹbọ sísun sí mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi kì yio ba ọ wi nitori ẹbọ rẹ, ọrẹ-ẹbọ sisun rẹ wà niwaju mi nigbagbogbo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi kí yóò bá ọ wí nítorí àwọn ìrúbọ Rẹ̀ tàbí ọrẹ̀ ẹbọ sísun Rẹ, èyí tí ó wà níwájú mi ní ìgbà gbogbo.