Psalms 51:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nígbà náà ni inú rẹ yóo dùn sí ẹbọ tí ó tọ́, ẹbọ sísun, ati ẹbọ tí a sun lódidi; nígbà náà ni a óo fi akọ mààlúù rúbọ lórí pẹpẹ rẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni inu rẹ yio dùn si ẹbọ ododo; pẹlu ọrẹ-ẹbọ sisun ati ọ̀tọtọ ọrẹ-ẹbọ sisun: nigbana ni nwọn o fi akọ-malu rubọ lori pẹpẹ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni inú Rẹ yóò dùn sí ẹbọ òdodo, pẹ̀lú ọrẹ-ẹbọ sísun àti ọ̀tọ̀tọ̀ ọrẹ ẹbọ sísun, nígbà náà ni wọn yóò fi akọ màlúù rúbọ lórí pẹpẹ Rẹ̀.