Psalms 52:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ títí lae, nítorí ohun tí o ṣe, n óo máa kéde orúkọ rẹ níwájú àwọn olùfọkànsìn rẹ, nítorí pé ó dára bẹ́ẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o ma yìn ọ lailai nitoripe iwọ li o ṣe e: emi o si ma duro de orukọ rẹ; nitori ti o dara li oju awọn enia mimọ́ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò yìn ọ títí fún ohun tí ó ti ṣe; èmí ní ìrètí nínú orúkọ Rẹ, nítorí orúkọ Rẹ dára. Èmi yóò yìn ọ́ níwájú àwọn ènìyàn mímọ́.