Psalms 53:6 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ìbá ti dára tó, kí ìgbàlà Israẹli ti Sioni wá! Nígbà tí Ọlọrun bá dá ire àwọn eniyan rẹ̀ pada, Jakọbu yóo yọ̀, inú Israẹli yóo sì dùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Tani yio fi igbala fun Israeli lati Sioni jade wá? Nigbati Ọlọrun ba mu igbekun awọn enia rẹ̀ pada wá, Jakobu yio yọ̀, inu Israeli yio si dùn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìgbàlà Ísírẹ́lì ìbá jáde wá láti Síónì! Nígbà tí Ọlọ́run bá mú ohun ìní àwọn ènìyàn Rẹ̀ padà, jẹ́ kí Jákọ́bù yọ̀ kí inú Ísírẹ́lì sì máa dùn!