Psalms 54:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé àwọn agbéraga dìde sí mi, àwọn ìkà, aláìláàánú sì ń lépa ẹ̀mí mi; wọn kò bìkítà fún Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitoriti awọn alejò dide si mi, awọn aninilara si nwá ọkàn mi: nwọn kò kà Ọlọrun si li oju wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn àlejò ń dìde sí mí. Àwọn aláìláàánú ènìyàn ń wá ayé mi àwọn ẹni tí kò ka Ọlọ́run sí ní ojú wọn.