Psalms 54:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ṣugbọn Ọlọrun ni olùrànlọ́wọ́ mi, OLUWA ni ó gbé ẹ̀mí mi ró.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, Ọlọrun li oluranlọwọ mi: Oluwa wà pẹlu awọn ti o gbé ọkàn mi duro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsí i Ọlọ́run ni Olùrànlọ́wọ́ mi; OLÚWA ní ẹni tí ó mú mi dúró, pa wọ́n run nínú òtítọ́ Rẹ.