Psalms 54:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Yóo san ẹ̀san ibi fún àwọn ọ̀tá mi; OLUWA, nítorí òtítọ́ rẹ, pa wọ́n run.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Yio si fi ibi san a fun awọn ọta mi: ke wọn kuro ninu otitọ rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí ibi padà sẹ́yìn sí àwọn tí ń sọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ sí mi; pa wọ́n run nínú òtítọ́ Rẹ.