Psalms 54:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
O ti yọ mí ninu gbogbo ìṣòro mi, mo sì ti fi ojú mi rí ìṣubú àwọn ọ̀tá mi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori o ti yọ mi kuro ninu iṣẹ́ gbogbo: oju mi si ri ifẹ rẹ̀ lara awọn ọta mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí ó yọ mí kúrò nínú ibi gbogbo ojú mi ti wo ìborí lórí ọ̀ta mi.