Psalms 55:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Tọ̀sán-tòru ni wọ́n ń yí orí odi rẹ̀ ká; ìwà ìkà ati ìyọnu ni ó sì pọ̀ ninu rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọsan ati oru ni nwọn fi nrìn odi rẹ̀ kiri: ìwa-ika pẹlu ati ikãnu mbẹ li arin rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọ̀sán àti oru ní wọ́n fí ń rìn gbogbo odi kiri; àrankàn àti èébú wà láàrin Rẹ̀.