Psalms 55:15 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Jẹ́ kí ikú jí àwọn ọ̀tá mi pa; kí wọ́n lọ sinu isà òkú láàyè; kí wọ́n wọ ibojì lọ pẹlu ìpayà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ki ikú ki o dì wọn mu, ki nwọn ki o si lọ lãye si isa-okú: nitori ti ìwa buburu mbẹ ni ibujoko wọn, ati ninu wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kí ikú kí ó dé bá wọn, Kí wọn ó lọ láàyè sí isà òkú, Jẹ́ kí wọn ó sọ̀kalẹ̀ sí ibojì pẹ̀lú ìpayà, nítorí tí ìwà búburú ń bẹ ní ibùjókòó wọn, àti nínú wọn.