Psalms 55:19 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ọlọrun tí ó gúnwà láti ìgbàanì yóo gbọ́, yóo sì rẹ̀ wọ́n sílẹ̀, nítorí pé wọn kò pa ìwà wọn dà, wọn kò sì bẹ̀rù Ọlọrun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ọlọrun yio gbọ́, yio si pọ́n wọn loju, ani ẹniti o ti joko lati igbani. Nitoriti nwọn kò ni ayipada, nwọn kò si bẹ̀ru Ọlọrun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọlọ́run yóò gbọ́ yóò sì pọ́n wọn lójú àní, ẹni tí ó ti jókòó láti ìgbà a nì— Sela Nítorí tí wọn kò ní àyípadà, tí wọn kò sì bẹ̀rù Ọlọ́run.